Ekaabo si ijo Emmanuel

Emmanuel Church Durham

A je ijo igbalode ati ijo Kiristiani to gbagbo ninu Bibeli. A ma n pade ni ilu Durham ati Chester-le Street. A fe je ijo to o dagba soke ati ijo fun gbogbo ebi ti o wo gbogbo agbalaya aiye.

A fe ni ilo siwaju a sife  idagba si ninu ise Olorun. Bi a seje ile olorun fun gbogbo ebi, ilekun wa si si fun gbogbo eyan. A ma n ki gbogbo eniyan kaabo bi ebi wa. A fe ko ile olorun pelu  awon ebun ti Olorun fi fun wa asi fe fi ayo wa han ni orisirisi  ona. A wa ni ilu Durham a si n wo awon ilu miran bi South Africa ati India.

Emmanuel Church Chester-le-Street

A ma n pade bi ijo ni ojo Aiku ni agogo  mewa abo. Awon Ijo  kekere  na ma n pade kakiri ilu Durham. Ninu awon ijo kekere  yi, a ye wa fun ibasepo ore ati igbani ni iyanju. A ni aye itoju fun awon omode ati  awon odo nigbati a ba pade ni ojo Aiku ati larin ose.

A je ara awon igbimo ijo Region Beyond. Awon eyan lati orilede gbogbo  ma n darapo mo wa. A wa na ma n ran awon eyan lo si awon orile ede miran. A ma nife lati pade yin fun nkan mimu ni ojo Aiku kato bere isin ni ago mewa  tabi leyin isin na.